Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 39:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Sedekiah, ọba Juda, ati gbogbo awọn ologun ri wọn, nigbana ni nwọn sá, nwọn si jade kuro ni ilu li oru, nwọn gba ọ̀na ọgbà ọba ati ẹnu-bode lãrin odi mejeji, nwọn si jade lọ li ọ̀na pẹtẹlẹ.

Ka pipe ipin Jer 39

Wo Jer 39:4 ni o tọ