Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 39:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọ, ki o si sọ fun Ebedmeleki, ara Etiopia, wipe: Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi pe, wò o, emi o mu ọ̀rọ mi wá sori ilu yi fun ibi, kì isi ṣe fun rere; nwọn o si ṣẹ niwaju rẹ li ọjọ na.

Ka pipe ipin Jer 39

Wo Jer 39:16 ni o tọ