Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 38:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mu Jeremiah, nwọn si sọ ọ sinu iho Malkiah ọmọ Hammeleki, ti o wà li agbala ile-túbu: nwọn fi okun sọ Jeremiah kalẹ sisalẹ. Omi kò si si ninu iho na, bikoṣe ẹrẹ̀: Jeremiah si rì sinu ẹrẹ̀ na.

Ka pipe ipin Jer 38

Wo Jer 38:6 ni o tọ