Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 38:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi awọn ijoye ba gbọ́ pe emi ti ba ọ sọ̀rọ, bi nwọn ba si wá sọdọ rẹ, ti nwọn sọ fun ọ pe, Sọ fun wa nisisiyi eyi ti iwọ ti sọ fun ọba, máṣe fi pamọ fun wa, awa kì o si pa ọ; ati eyi ti ọba sọ fun ọ pẹlu:

Ka pipe ipin Jer 38

Wo Jer 38:25 ni o tọ