Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 38:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si mu gbogbo awọn aya rẹ ati awọn ọmọ rẹ jade tọ awọn ara Kaldea lọ: iwọ kì yio si sala kuro li ọwọ wọn, ọwọ ọba Babeli yio si mu ọ: iwọ o si mu ki nwọn ki o fi iná kun ilu yi.

Ka pipe ipin Jer 38

Wo Jer 38:23 ni o tọ