Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 38:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jeremiah sọ fun Sedekiah pe; Bayi li Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wi pe: Bi iwọ o ba jade nitõtọ tọ̀ awọn ijoye ọba Babeli lọ, nigbana ni ọkàn rẹ yio yè, a ki yio si fi iná kun ilu yi; iwọ o si yè ati ile rẹ.

Ka pipe ipin Jer 38

Wo Jer 38:17 ni o tọ