Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 37:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Sedekiah, ọba ranṣẹ pè e: ọba si bere lọwọ rẹ̀ nikọkọ ni ile rẹ̀, o si wipe, Ọ̀rọ ha wà lati ọdọ Oluwa? Jeremiah si wipe, O wà: o wi pe, nitori a o fi ọ le ọwọ ọba Babeli.

Ka pipe ipin Jer 37

Wo Jer 37:17 ni o tọ