Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 37:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si wà li ẹnu-bode Benjamini, balogun iṣọ kan wà nibẹ, orukọ ẹniti ijẹ Irijah, ọmọ Ṣelemiah, ọmọ Hananiah; on si mu Jeremiah woli, wipe, Iwọ nsa tọ̀ awọn ara Kaldea lọ.

Ka pipe ipin Jer 37

Wo Jer 37:13 ni o tọ