Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 36:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jeremiah mu iwe-kiká miran, o si fi i fun Baruku, akọwe, ọmọ Neriah; ẹniti o kọwe sinu rẹ̀ lati ẹnu Jeremiah gbogbo ọ̀rọ iwe ti Jehoiakimu, ọba Juda ti sun ninu iná: a si fi ọ̀rọ pupọ bi iru eyi kún ọ̀rọ iwe na pẹlu.

Ka pipe ipin Jer 36

Wo Jer 36:32 ni o tọ