Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 36:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si rán Jehudu lati lọ mu iwe-kiká na wá: on si mu u jade lati inu iyara Eliṣama, akọwe. Jehudu si kà a li eti ọba, ati li eti gbogbo awọn ijoye, ti o duro tì ọba.

Ka pipe ipin Jer 36

Wo Jer 36:21 ni o tọ