Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 36:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sọkalẹ lọ si ile ọba, sinu iyara akọwe, si wò o, gbogbo awọn ijoye joko nibẹ, Eliṣama, akọwe, ati Delaiah, ọmọ Semaiah, ati Elnatani, ọmọ Akbori, ati Gemariah, ọmọ Safani, ati Sedekiah, ọmọ Hananiah, ati gbogbo awọn ijoye.

Ka pipe ipin Jer 36

Wo Jer 36:12 ni o tọ