Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 35:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li awa gbà ohùn Jonadabu, ọmọ Rekabu, baba wa gbọ́ ninu gbogbo eyiti o palaṣẹ fun wa, ki a má mu ọti-waini ni gbogbo ọjọ wa, awa, awọn aya wa, awọn ọmọkunrin wa, ati awọn ọmọbinrin wa;

Ka pipe ipin Jer 35

Wo Jer 35:8 ni o tọ