Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 34:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o kú li alafia: ati bi ijona-isinkú awọn baba rẹ, awọn ọba igbãni ti o wà ṣaju rẹ, bẹ̃ni nwọn o si ṣe ijona-isinkú fun ọ, nwọn o si pohunrere rẹ, pe, Yẽ oluwa! nitori eyi li ọ̀rọ ti emi ti sọ, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 34

Wo Jer 34:5 ni o tọ