Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 34:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa wi, Ẹnyin kò feti si mi, ni kikede omnira, ẹgbọ́n fun aburo rẹ̀, ati ẹnikini fun ẹnikeji rẹ̀: wò o, emi o kede omnira fun nyin, li Oluwa wi, si idà, si ajakalẹ-àrun, ati si ìyan, emi o si fi nyin fun iwọsi ni gbogbo ijọba ilẹ aiye.

Ka pipe ipin Jer 34

Wo Jer 34:17 ni o tọ