Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 34:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li opin ọdọdun meje ki olukuluku enia jẹ ki arakunrin rẹ̀ ki o lọ, ani ara Heberu ti o ta ara rẹ̀ fun ọ; yio si sìn ọ li ọdun mẹfa, nigbana ni iwọ o jẹ ki o lọ lọfẹ lọdọ rẹ: ṣugbọn awọn baba nyin kò gbọ́ temi, bẹ̃ni wọn ko tẹti wọn silẹ.

Ka pipe ipin Jer 34

Wo Jer 34:14 ni o tọ