Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 34:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn lẹhin na nwọn yi ọkàn pada, nwọn si mu ki awọn iranṣẹkunrin ati awọn iranṣẹbinrin, awọn ẹniti nwọn ti jẹ ki o lọ lọfẹ, ki o pada, nwọn si mu wọn sin bi iranṣẹkunrin ati bi iranṣẹbinrin.

Ka pipe ipin Jer 34

Wo Jer 34:11 ni o tọ