Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 32:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enia yio fi owo rà oko, nwọn o kọ ọ sinu iwe, nwọn o si dí i, nwọn o si pe awọn ẹlẹri ni ilẹ Benjamini, ati ni ibi wọnni yi Jerusalemu ka, ati ni ilu Juda, ati ni ilu ọwọ́-oke na, ati ni ilu afonifoji, ati ni ilu iha gusu; nitori emi o mu igbekun wọn pada wá, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:44 ni o tọ