Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 32:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Sedekiah, ọba Juda, kì yio bọ́ li ọwọ awọn ara Kaldea, ṣugbọn a o fi i le ọwọ ọba Babeli, Lõtọ, yio si ba a sọ̀rọ li ojukoju, oju rẹ̀ yio si ri oju rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:4 ni o tọ