Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 32:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kọ́ ibi giga Baali, ti o wà ni afonifoji ọmọ Hinnomu, lati fi awọn ọmọkunrin wọn ati awọn ọmọbinrin wọn fun Moleki; ti emi kò paṣẹ fun wọn, bẹ̃ni kò wá si ọkàn mi, pe ki nwọn ki o mã ṣe ohun irira yi, lati mu Juda ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:35 ni o tọ