Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 32:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn ọmọ Israeli ati awọn ọmọ Juda ti ṣe kiki ibi niwaju mi lati igba èwe wọn wá: nitori awọn ọmọ Israeli ti fi kiki iṣẹ ọwọ wọn mu mi binu, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:30 ni o tọ