Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 32:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wipe, Mu iwe wọnyi, iwe rirà yi, ti a dí, ati iwe yi ti a ṣi silẹ; ki o si fi wọn sinu ikoko, ki nwọn ki o le wà li ọjọ pupọ.

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:14 ni o tọ