Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 31:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, emi o mu wọn lati ilẹ ariwa wá, emi o si kó wọn jọ lati àgbegbe ilẹ aiye, afọju ati ayarọ pẹlu wọn, aboyun ati ẹniti nrọbi ṣọkan pọ̀: li ẹgbẹ nlanla ni nwọn o pada sibẹ.

Ka pipe ipin Jer 31

Wo Jer 31:8 ni o tọ