Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 31:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn eyi ni majẹmu ti emi o ba ile Israeli da; Lẹhin ọjọ wọnni, li Oluwa wi, emi o fi ofin mi si inu wọn, emi o si kọ ọ si aiya wọn; emi o si jẹ Ọlọrun wọn, awọn o si jẹ enia mi.

Ka pipe ipin Jer 31

Wo Jer 31:33 ni o tọ