Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 31:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, pe gẹgẹ bi emi ti ṣọ́ wọn, lati fà tu, ati lati fa lulẹ, ati lati wo lulẹ, ati lati parun, ati lati pọnloju, bẹ̃ni emi o ṣọ́ wọn, lati kọ́, ati lati gbìn, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 31

Wo Jer 31:28 ni o tọ