Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 31:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ ọ̀wọn ha ni Efraimu fun mi bi? ọmọ inu-didùn ha ni? nitori bi emi ti sọ̀rọ si i to, sibẹ emi ranti rẹ̀, nitorina ni ọkàn mi ṣe lù fun u; emi o ṣe iyọ́nu fun u nitõtọ, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 31

Wo Jer 31:20 ni o tọ