Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SA wò o, bi a wipe ọkunrin kan kọ̀ aya rẹ̀ silẹ, ti aya na si kuro lọdọ rẹ̀, ti o si di aya ẹlomiran, ọkunrin na le tun tọ̀ ọ wá? ilẹ na kì yio di ibajẹ gidigidi? ṣugbọn iwọ ti ba ayanfẹ pupọ ṣe panṣaga, iwọ o tun tọ̀ mi wá! li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 3

Wo Jer 3:1 ni o tọ