Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ si mã wá alafia ilu na, nibiti emi ti mu ki a kó nyin lọ ni igbekun, ẹ si mã gbadura si Oluwa fun u: nitori ninu alafia rẹ̀ li ẹnyin o ni alafia.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:7 ni o tọ