Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa ti fi ọ jẹ oyè alufa ni ipo Jehoiada, alufa, ki ẹnyin ki o lè jẹ olutọju ni ile Oluwa, nitori olukuluku aṣiwere enia, ati ẹnikẹni ti o sọ asọtẹlẹ ki iwọ ki o le fi wọn sinu tubu ati sinu àba.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:26 ni o tọ