Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o di ríri fun nyin, li Oluwa wi: emi o si yi igbekun nyin pada kuro, emi o si kó nyin jọ lati gbogbo orilẹ-ède ati lati ibi gbogbo wá, nibiti emi ti lé nyin lọ, li Oluwa wi; emi o si tun mu nyin wá si ibi ti mo ti mu ki a kó nyin ni igbekun lọ.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:14 ni o tọ