Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi pe, Lẹhin ti ãdọrin ọdun ba pari ni Babeli, li emi o bẹ̀ nyin wò, emi o si mu ọ̀rọ rere mi ṣẹ si nyin, ni mimu nyin pada si ibi yi.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:10 ni o tọ