Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI si li ọ̀rọ iwe ti Jeremiah woli rán lati Jerusalemu si iyokù ninu awọn àgba ti o wà ni igbèkun, ati si awọn alufa, ati awọn woli, ati si gbogbo enia ti Nebukadnessari kó ni igbekun lọ lati Jerusalemu si Babeli.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:1 ni o tọ