Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 28:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi: emi ti fi ajaga irin si ọrùn gbogbo orilẹ-ède wọnyi, ki nwọn ki o sin Nebukadnessari, ọba Babeli, nwọn o si sin i, emi si fi ẹranko igbẹ fun u pẹlu.

Ka pipe ipin Jer 28

Wo Jer 28:14 ni o tọ