Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 28:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọdun kanna li atetekọbẹrẹ ijọba Sedekiah, ọba Juda, li ọdun kẹrin ati oṣù karun, ti Hananiah, ọmọ Asuri woli, ti iṣe ti Gibeoni, wi fun mi ni ile Oluwa, niwaju awọn alufa ati gbogbo enia pe,

Ka pipe ipin Jer 28

Wo Jer 28:1 ni o tọ