Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 23:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ẹnyin ba wipe, ọ̀rọ-wuwo Oluwa, nitorina, bayi li Oluwa wi, nitori ẹnyin nsọ ọ̀rọ yi pe, ọ̀rọ-wuwo Oluwa ti emi si ranṣẹ si nyin pe ki ẹ máṣe wipe: ọ̀rọ-wuwọ Oluwa;

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:38 ni o tọ