Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 23:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli, wi si oluṣọ-agutan wọnni, ti nṣọ enia mi; Ẹnyin tú agbo-ẹran mi ká, ẹ le wọn junù, ẹnyin kò si bẹ̀ wọn wò, sa wò o, emi o bẹ̀ nyin wò nitori buburu iṣe nyin, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:2 ni o tọ