Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 23:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi: Ẹ máṣe feti si ọ̀rọ awọn woli ti nsọ asọtẹlẹ fun nyin: nwọn sọ nyin di asan, nwọn sọ̀rọ iran inu ara wọn, kì iṣe lati ẹnu Oluwa.

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:16 ni o tọ