Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 22:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe sọkun fun okú, bẹ̃ni ki ẹ máṣe pohùnrere rẹ̀, ṣugbọn ẹ sọkun ẹ̀dun fun ẹniti o nlọ, nitori kì yio pada wá mọ, kì yio si ri ilẹ rẹ̀ mọ.

Ka pipe ipin Jer 22

Wo Jer 22:10 ni o tọ