Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 2:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn alufa kò wipe, Nibo li Oluwa wà? ati awọn ti o mu ofin lọwọ kò mọ̀ mi: awọn oluṣọ si ṣẹ̀ si mi, ati awọn woli sọ asọtẹlẹ nipa Baali, nwọn si tẹle ohun ti kò lerè.

Ka pipe ipin Jer 2

Wo Jer 2:8 ni o tọ