Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ìwa-buburu rẹ ni yio kọ́ ọ, ipadasẹhin rẹ ni yio si ba ọ wi: mọ̀, ki iwọ si ri i pe, ohun buburu ati kikoro ni, pe, iwọ ti kò Oluwa Ọlọrun rẹ, ati pe ìbẹru mi kò si si niwaju rẹ; li Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun wi.

Ka pipe ipin Jer 2

Wo Jer 2:19 ni o tọ