Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 19:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si wipe, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa, ẹnyin ọba Juda, ati olugbe Jerusalemu; Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wi: sa wò o, emi o mu ibi wá sihin yi, eyiti eti gbogbo awọn ti o ba gbọ́ ọ, yio ho.

Ka pipe ipin Jer 19

Wo Jer 19:3 ni o tọ