Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 17:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni ki ẹ má si ṣe gbe ẹrù jade kuro ninu ile nyin li ọjọ isimi, bẹ̃ni ki ẹ má ṣe iṣẹkiṣẹ, ṣugbọn ki ẹ yà ọjọ isimi si mimọ́, gẹgẹ bi mo ti paṣẹ fun awọn baba nyin.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:22 ni o tọ