Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 17:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki oju ki o tì awọn ti o nṣe inunibini si mi, ṣugbọn má jẹ ki oju ki o tì mi: jẹ ki nwọn ki o dãmu, ṣugbọn máṣe jẹ ki emi ki o dãmu: mu ọjọ ibi wá sori wọn, ki o si fi iparun iṣẹpo meji pa wọn run.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:18 ni o tọ