Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 13:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ti ri panṣaga rẹ, ati yiyan rẹ bi ẹṣin, buburu ìwa-agbere rẹ, ati ìwa irira rẹ lori oke ati ninu oko. Egbe ni fun ọ, iwọ Jerusalemu! iwọ kò le di mimọ́, yio ha ti pẹ to!

Ka pipe ipin Jer 13

Wo Jer 13:27 ni o tọ