Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 11:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani mo dabi ọdọ-agutan ti o mọ̀ oju ile, ti a mu wá fun pipa: emi kò si mọ̀ pe, nwọn ti pinnu buburu si mi wipe: Jẹ ki a ke igi na pẹlu eso rẹ̀ ki a si ke e kuro ni ilẹ alãye, ki a máṣe ranti orukọ rẹ̀ mọ.

Ka pipe ipin Jer 11

Wo Jer 11:19 ni o tọ