Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani kì ba bẹ̀ru rẹ, Iwọ Ọba orilẹ-ède? nitori tirẹ ni o jasi; kò si ninu awọn ọlọgbọ́n orilẹ-ède, ati gbogbo ijọba wọn, kò si ẹniti o dabi Iwọ!

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:7 ni o tọ