Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki emi ki o to dá ọ ni inu, emi ti mọ̀ ọ, ki iwọ ki o si to ti inu jade wá li emi ti sọ ọ di mimọ́, emi si yà ọ sọtọ lati jẹ́ woli fun awọn orilẹ-ède.

Ka pipe ipin Jer 1

Wo Jer 1:5 ni o tọ