Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢUGBỌN iṣuju na kì yio wà nibiti wahalà mbẹ nisisiyi, gẹgẹ bi ìgba iṣãju ti mu itìju wá si ilẹ Sebuloni ati ilẹ Naftali, bẹ̃ni ìgba ikẹhin yio mu ọla wá si ọ̀na okun, niha ẹkùn Jordani, Galili awọn orilẹ-ède.

Ka pipe ipin Isa 9

Wo Isa 9:1 ni o tọ