Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 66:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o yà ara wọn si mimọ́, ti nwọn si sọ ara wọn di mimọ́ ninu agbala wọnni, ti ọkan tẹle ekeji li ãrin, nwọn njẹ ẹran ẹlẹdẹ, ati ohun irira, ati eku, awọn li a o parun pọ̀; li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Isa 66

Wo Isa 66:17 ni o tọ