Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 66:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BAYI ni Oluwa wi, pe, Ọrun ni itẹ́ mi, aiye si ni apoti itisẹ̀ mi: nibo ni ile ti ẹ kọ́ fun mi gbé wà? ati nibo ni isimi mi gbe wà?

Ka pipe ipin Isa 66

Wo Isa 66:1 ni o tọ