Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 65:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki ẹnyin ki o yọ̀, ki inu nyin ki o si dùn titi lai ninu eyi ti emi o da: nitori kiyesi i, emi o da Jerusalemu ni inudidùn, ati awọn enia rẹ̀ ni ayọ̀.

Ka pipe ipin Isa 65

Wo Isa 65:18 ni o tọ